Yoruba

ASA IGBEYAWO

Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran (perseverance) Suuru (patience) Ipamora (tolerance) Igbora-eni-ye (understanding) Ife aisetan (unconditional love)   IGBESE IGBEYAWO Ifojusode Iwaadi Alarina Isihun / ijohen Itoro Baba gbo, iya gbo

ASA IGBEYAWO Read More »

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)

IGBESE LETA AIGBEFE Adiresi: Adiresi akoleta (The writer’s address) Adiresi agbaleta (Receiver’s address) Deeti (the day’s date) iii. Ikini ibeere (salutation) Akole leta (the tittle / heading) Koko leta (main content) Ikadii / ipari leta (conclusion)   Leta aigbagbefe / aigbefe (Formal letter) Eyi ni leta ti a maa n ko si awon eniyan ti

AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER) Read More »

OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI

ASA IGBEYAWO ATIJO (IBILE) IGBESE IGBEYAWO                                 ALAYE Ifojusode                    Awon obi okunrin yoo maa fi oju sile wa obinrin. Iwadii                         Won yoo se iwadii idile obinrin naa ni aarin ilu. Won yoo tun se, iwadi lowo ifa. Alarina                       Alarina ni won yoo maa ran si ara won (oko ati Iyawo afesona), Boko ba moju

OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI Read More »

SILEBU EDE YORUBA

AKOONU Silebu ni ege oro ti o kere ju ti eemi le gbe jade leekan soso. Apeere: Ajayi:              A-ja-yi  =         silebu meta Olabisi             O-la-bi-si         silebu merin. Adeleke           A-de-le-ke       silebu merin Olopaa             O-lo-pa-a         silebu merin Gbangbadekun  gba-n-gba-de-kun     silebu marun-un.   Odo Silebu: ni apa ti o se pataki julo ninu ihun silebu kookan. Iro

SILEBU EDE YORUBA Read More »