Skip to content

Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Bi apeere:

Ade ra iwe ede Yoruba

Tuned gun igi osan

“ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii:

Abuda oro – ise

  1. Oro – ise ni o maa n je yo leyin oluwa. Apeere:

Ade je moinmoin

Nike feran ese

  1. Oro ti o ba tele atoka iyisodi ko lo gbodo je oro –ise. Apeere:

Bola ko je iyan

Sunkanmi o wa

Eya/ orisii oro – ise

  1. ORO – ISE KIKUN: Oro – ise ti o le da duro ti o sin i itumo kikun lai sip e a fi oro – ise miiran kun un. Bi apeere:

Sade lo

Bisi sun

Kolade rerin-in

Oro – ise kikun le je

  1. Oro – ise agbabo

oro – ise agbabo ni awon oro – ise ti won ko le sai gbabo ninu gbolohun. Bi apeere:

mo de ikoko

bisi ra iyo

kikelomo je eja

 

See also

YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *