OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI
ASA IGBEYAWO ATIJO (IBILE) IGBESE IGBEYAWO ALAYE Ifojusode Awon obi okunrin yoo maa fi oju sile wa obinrin. Iwadii Won yoo se iwadii idile obinrin naa ni aarin ilu. Won yoo tun se, iwadi lowo ifa. Alarina Alarina ni won yoo maa ran si ara won (oko ati Iyawo afesona), Boko ba moju […]
OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI Read More »