AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI
Aroko ti a ko to da lori itakuroso laaarin eniyan meji tabi ju bee lo ni a n pen i aroko oni-soro-n-gbesi. Abuda Aroko Onisoro-n-gbesi O maa n ni akopa bii ere ori itage Oro enu akopa kookan maa n han ni iwaju oruko won Iso bee ko gbodo gun ju, ko si se regi […]
AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI Read More »