AKOONU
Silebu ni ege oro ti o kere ju ti eemi le gbe jade leekan soso. Apeere:
Ajayi: A-ja-yi = silebu meta
Olabisi O-la-bi-si silebu merin.
Adeleke A-de-le-ke silebu merin
Olopaa O-lo-pa-a silebu merin
Gbangbadekun gba-n-gba-de-kun silebu marun-un.
Odo Silebu: ni apa ti o se pataki julo ninu ihun silebu kookan. Iro faweli ati iro
konsonanti aranmupe asesilebu ni o maa n sise gege bi odo silebu. Odo silebu ni o maa n dun ju ninu silebu.
Awon iro odo silebu ni a maa n gbo ju ninu oro.
Ori odo silebu ni a maa n fi ami ohun si
Kan-an-n-pa ni odo silebu je ninu ihun silebu.
Ap
wa
gba
sun
Apaala silebu -;je iro konsonanti yato si konsonanti aranmupe asesilebu [m,n] ni o maa n sise gege bi apaala silebu.
ap
gbo
dun
ko
we
IHUN SILEBU [F1,KF ATI N] NINU ORO OLOPO SILEBU.
Orisiirisii ona ni a le gba se ihunpo silebu ninu oro olopo silebu.
ORO IHUN IYE SILEBU
Aso A/ so 2
f /kf
Bata ba / ta 2
Kf / kf
Igbale i/gba / le 3
F/ kf /kf
Alupupu A/lu/pu/pu 4
f/kf/kf/ kf
Konko ko/N/ko 3
Kf/N/kf
IGBELEWON
- Kin ni silebu?
- Salaye ihun silebu pelu apeere.
- Pin awon oro yii si silebu
Agbalagbaakan
Olowolayemo
Gbangbalakoogbo
Oji ku tu ba-ra orunsaaro
Operekete
IGBELEWON
- Salaye ni ekunrere lori odo silebu ati apaala silebu pelu apeere.
- Eya ihun silebu meloo ni o wa? Fi apeere gbe idahun re lese.
- Ki ni pataki konsonanti aranmupe n ati m ninu ege silebu?
IWE AKATILEWA
Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.
See also
AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN
AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE
AKOLE ISE: AWON LITIRESO APILEKO ERE-ONITAN
AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE
AKOLE ISE: ASA ATI OHUN ELO ISOMOLORUKO
E seun pupo sa
Great
Thank you