ASA IGBEYAWO
Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran (perseverance) Suuru (patience) Ipamora (tolerance) Igbora-eni-ye (understanding) Ife aisetan (unconditional love) IGBESE IGBEYAWO Ifojusode Iwaadi Alarina Isihun / ijohen Itoro Baba gbo, iya gbo […]