Oro Oruko:- Oro Oruko ni awon oro ti won le da duro ni ipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun.
Ise Oro-Oruko
- Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun – Oluwa ni oluse nnkan ninu gbolohun apeere;
- Ayinde ra aso
- Ojo je ewa
- Oro oruko maa n wa ni ipo abo ninu gbolohun – Eyi ni eni ti a se nnkan si ninu gbolohun. Apeere;
- Mo ra oko
- Onilu lu ilu
- Oro-Oruko maa n se ise eyan fun oro oruko miiran. Apeere;
- Baba agbe ge igi
- Kunle oluko na yemi
- Binpe pa ejo obokun
- Oro-Oruko tun maa n sise abo fun oro-atokun. Apeere;
- Ade lo si oja
- Emi lo ba ni ile
ORO AROPO ORUKO:-Eyi ni awon oro ti a n lo dipo oro oruko ninu gbolohun.
Ise Oro Aropo – Oruko
- Oro Aropo- Oruko le se ise oluwa ninu gbolohun. A le pin-in si ipo eyo ati opo
Eni Eyo Opo
Kin-in-ni Mo/n ‘A’
Keji O E
Keta O Won
Apeere;
- Mo je ebe Eyi eni kin-in-ni
n o je eba
- A je eba – opo eni kin-in-ni
- Oro aropo-oruko le se ise abo ninu oro-ise ninu gbolohun.
Eyo opo
Eni kin-in-ni Mi Wa
Eni Keji O/E Yin
Eni keta Afaagun faweli won
Apeere;
Eni kin-in-ni
- Tolu ri mi – eyo
Tolu ri wa – opo
Eni keji
- Orun pa o
orun pa e
orun pa yin – opo
eni keta
iii. O so fun un
Ade gbe e
- Oro aropo-oruko maa n se ise eyan ninu gbolohun
Eyo Opo
Eni kin-in-ni ‘Mi’ wa
Eni keji re/e yin
Eni keta Re/e won
Apeere
Aso re wu mi – Eni keta eyo
Igba gbe se won – eni keta opo
Ile yin dara – eni keji opo.
Igbelewon:-
(i) So itumo oro oruko ati oro aropo oruko
(ii) Ko ise oro-oruko ati aropo oro meji meji pelu apeere
ISE ASETILEWA:-
- ko isori awon oro yoruba inu gbolohun wonyii jade.
- Mo ra epa
- Oluko na mi
D Mo ri gbogbo yin
E Eyin re funfun bii egbon owu
- Ile wa gbayi o gbeye
- Yoruba akayege iwe Amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe kin-in-ni lati owo o L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki. Oju iwe ogun Eko kerindinlogun
LITRESO – Litreso Apileko Oloro geere ti ijoba yan. Ewi Yoruba lakotun fun ile iwe sekondiri kekere lati owo M.A,Olowu ati awon akeegbe re.
Igbelewon:-
(i) Iwe itan apileko oloro geere wo ni a yan fun kika ni taamu yin?
(ii) Ta ni onkowe iwe naa?
ISE ASETILEWA:- Ewi Yoruba Lakootun(ibeere ewi ti a ka)
See also:
AKOLE ISE- EDE: AROKO ATONISONA ONIROYIN (NARRATIVE ESSAY)
Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence)
Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba
Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi
Ede:- ilana Kika akaye onisorongbesi