Foniimu konsonanti
Foniimu faweli ati ohun
Eda foniimu konsonanti ati faweli
Akoonu
(Iro aseyato)
Foniimu ni awon iro ti o le fi iyato han laaarin oro kan tabi omiran
Ap
Foniimu ni /b/ /d/ /t/, eyi ti o tumo si pe bi a ba fi iro kan dipo ikeji iyato yoo wa
Ap
Ede
Ere
Epe
Ege
Egbe
Idako foonu faweli – a {a}
Baba ko ebe – {baba k כ ebe}
Foniimu ede Yoruba pin si ona meta
- Foniimu konsonanti
- Foniimu faweli
- Foniimu ohun
- Foniimu konsonanti -: iro aseyato ni gbogbo iro konsonanti ede Yoruba fere je ba, pa, wa
Ap
/b/ ni eda {b} – to je konsonanti akunyun afeji – ete – pe asenupe.
O le jeyo nibi gbogbo ap bo /b כ[b כ
Foniimu Faweli: naa je iro aseyato bi a ba fi faweli kan ropo ikeji iyato yoo wa ninu oro naa.
Ap.
Wa
Wo
We
Foniimu faweli pin si ona meji
Faweli airanmupe
Faweli aranmupe
Apejuwe fonimu faweli
/a/ ni eda [a] – ayanupe, aarin, perese
o maa n jeyo nibi gbogbo ap s /Sa/ [Sa]
apa /akpa/ [akpa]
FONIIMU OHUN
Iro ohun a maa je foniimu tabi toniimu. Eyi nipe ohun ori silebu kan le mu ki oro kan yato si ikeji paapaa ninu ede olohun bii ede Yoruba.
Foniimu ohun pin si ona meta.
- / | / toniimu oke ap Ja
- | \ | toniimu isale ap iwa
- toniimu aarin
ap
wi
wa
so
igba (re re)
igba (garden egg)
igba (time)
igba (calabash)
Eda Foniimu :- ni awon iro ti ko le fi iyato han laarin itumo oro kan ati omiran. Eda foniimu je ifonka alaiseyato ninu ede Yoruba.
Apeere eda foniimu faweli in
\ I/ ati / n/
eyi ni pe bi a ba fi won ropo ara won ninu oro ko ni si iyato.
Ap.
ni aya – laya
ni ana – I anaa
mo ni aso – mo laso.
Ogunbambo – Ogunbanbo
Oronbo – Orombo.
O kan je eda ikeji bee ni ko si iyato kankan laarin won.
Eda faweli: eda faweli foniimu faweli ede Yoruba ni / a / an ati כ// on.
Ap
Itan – Iton
Iran – Iren
Okan – Okon
IGBELEWON
- ki ni foniimu? Salaye ni ekunrere.
- Ki ni eda foniimu? Salaye ni ekunrere.
- Fun fonoloji ni oriki.
IWE AKATILEWA
Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.
{BZTQLQ/)R*XZ]NLQ
Itan so nipa Obatala wi pe oun ni ipo re ga julo ninu gbogbo orisa. Oun ni o lagbara julo ninu won, oun si ni asaaju won patapata. Oruko meji ni a le pe orisa yii nile Yoruba. A le pe e ni Obatala, eyi ti o ja si ‘Oba ti ala’, a tun le pe e ni Orisa-nla eyi ti o ja si ‘Oba ti-o-nla’, Oba ti o tobi.
Oun kan naa ni a gbo pe o je igba keji eledaa Olodumare. O di igba keji nitori pe oun gan-na ni Eledaa koko da. Leyin eyi ni Eledaa fun un ni agbara lati ran oun lowo ninu ise re gege bi Eledaa. A gbo pe Obatala ni i se oju, imu, enu, eti ati awon eya ara yooku leyin ti Eledaa ba ti da ara borogidi tan.
Awon aro, amunkun, afin, abuke, afoju ati awon miiran bee la n pe ni ‘eni orisa’.
Awon wonyi ni Obatala fi ise tabi owo agbara re han. A sit un n pe e ni ‘Alamo Rere’ nitori pe o ni anfaani lati lo amo re fun siseda eniyan. Igbagbo awon oloosa Obatala nip e bi Olodumare ba se ara tan, yoo fi ara naa ranse si Obatala ki o tan eda naa wa si aye, ti yoo si maa so titi ojo aye re.
Obatala ko fe epo, osun bi ko se ala. Aso funfun ni awon aworo Obatala ati awon olusin re maa n lo ni ojo odun re. Iyan ati obe funfun ni ti Obatala, inu igba funfun ni a o de iyan re si. Obe ti a fi eran igbin ati ori se ni ti Obatala. Aso funfun gele funfun ileke fun ni iyawo Obatala sa maa n lo ni ojo odun re.
IGBELEWON
Salaye orisa Orunmila.
IWE ITOKASI
Olu, D. ati Jeje, A. (1970) AWON ASA ATI ORISA ILE YORUBA Onibonoje Press.
IFA
Nigba ti a ba daruko Ifa, okan opolopo eniyan ni o maa n lo si odo Orunmila. Looto ni Orunmila je baba Ifa sugbon kii se oun nikan ni Ifa ti a n d anile Yoruba.
Ni aye atijo ko si ohunkohun ti a le se nile Yoruba lailo beere lodo Ifa. Ti a ba fe fe iyawo, a o lo beere boya wundia ti okan wa so ni yoo je iyawo rere abi bee ko. Bi a ba bimo a nila ti lo beere esentaye omo lodo Ifa abbl. Awon ohun ti a n se nile Yoruba ti a kii fi ti Ifa si ko wopo. Owo Ifa ni a ti n beere eni ti o maa j’Oba ohun ni o mo eni ti yoo yooku ni aarin ilu. Paripari re ni wi pe owo Ifa ni a ti beere ojo ti o ba to ti o si ye lati bo Ifa ni odun. Eleyi fi han kedere lori ipo ti awon Yoruba fi ifa si.
Yato si orunmila, awon Ifa miiran ti o wa ni ile Yoruba ni Agbigba, obi, Ile, olokun, Olokun-awo, wo-mi-pee.
Awon onitan so fun wa pe Orunmila ni eni naa ti o Olodumare ran lati wa se igba keji re ni aye. Odo re ni a o ti maa beere orisii nnkan nitori o je eni ti o gbon lopolopo. Awon tile so pe o wa nibe nigba ti Olodumare da gbogbo ohun ti o n be ninu aye pelu eniyan paapaa idi re e ti a fi n pe e ni Eleri-ipin. Apeja oruko Orunmila ni ‘Orun-mo-eni-ti-o-maa-la’
Itan kan so w ape o ni baba ati iya sugbon won ko gbe ile aye pelu re. )rok9 ni or5k[ bzbq Zlqj3ru ni or5k[ 8yq r2 ni 0de =run. +sany8n j1 oluran lowo pztzk8 f5n +r5nm8lz.
Ekuro ni Ifa ti o j1 irinsc f5n +r5nm8lz. Ifa je irinse fun +r5nm8lz. Awon babalawo ni o je aworo Orunmila tabi Ifa.
IGBELEWON
Salaye iyato ti o wa laarin orunmila ati Ifa.
IWE ITOKASI
Olu, D. ati Jeje, A. (1970) AWON ASA ATI ORISA ILE YORUBA Onibonoje Press.
LITIRESO
Kika iwe ti ijoba yan
IGBELEWON
- Kin ni foniimu
- Ona meloo ni foniimu pin sii
- Se agekuru ohun ti e ka ninu iwe adakedajo.
IWE AKATILEWA
Imo Ede Asa ati Litreso Yoruba SS3. S.Y Ademoyin o.i 83 – 90
APAPO IGBELEWON
- Salaye orisa Orunmila.
- ki ni foniimu? Salaye ni ekunrere.
- Ki ni eda foniimu? Salaye ni ekunrere.
- Fun fonoloji ni oriki.
ATUNYEWO EKO
Ko iyato merin laarin iro konsonanti ati iro faweli sile.
ISE ASETILEWA
- Foniimu ni _______ (a) iro ti a pe (b) to le fi iyato han (d) iro ti o dun
- Faweli pin si ona ____ (a) meji (b) meta (d) merin
- Iro ______ naa ni a mo si toniimu (a) faweli (b) konsonanti (d) ohun
- eda foniimu konsonanti ni _______ (a) / b/ ati / d/ (b) /i/ ati m (d) /I/ ati / n/
- Idako ‘on’ ni _____ (a) / on / (b) /c/ (d) / כ
APA KEJI
- Pelu apeere salaye iyato to wa laarin iro foniimu ati eda foniimu .
- Se adako – foonu fun awon faweli ti a fala si nidi ninu awon oro wonyi: Imu, Won, Yen,
Esin, Aso, Eyele, ati Sola lo si ile ijosin.
- Salaye iyato ti o wa laarin Obatala ati Orunmila.
See also
ASA ELEGBEJEGBE
AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN
AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE
AKOLE ISE: AWON LITIRESO APILEKO ERE-ONITAN