Eyan ni awon wunren (oro) ti a fi n yan oro – oruko (noun) tai apola oruko (Noun phrase) ninu gbolohun tabi ninu isori. Bi apeere:
Iwe tuntun ni a f era
Aso ala ni mo wo
‘Tuntun’ ati ‘ala’ ti a fa ila si ninu gbolohun oke yii ni oro eyon ti o n se afikun itumo fun oro oruko ti won n yan.
Orisii eyan
- Eyan asapejuwe
- Eyan ajoruko
- Eyan asafihan
- Eyan asonka
- Eyan alawe gbolohun asapejuwe
- EYAN ASAPEJUWE: Ise eyan yii ni lati pon oro oruko lona ti yoo fi ye ni tekeyeke. Oro apejuwe pin si ona meji, awon ni:
- Oro apejuwe ipile: iwonyi ni awon oro bii; pupa, rere, dudu, kekere, nla, funfun abbl.
Apeere lilo ni gbolohun
Nike je omo rere
Amala dudu ni mo feran
Ounje kekere ko le yo mi
- EYAN AJORUKO: Eyi ni oro oruko tabi oro aropo oruko ti a lo lati yan oro – oruko miiran. Bi apeere: Dokita oyinbo ni mo fe ri
Abule odu ni Busola n gbe
Ewure Torera ni ole ji
Ile wa ni a n lo
- EYAN ASOFIHAN: Eyi maa n toka si ohun ti a n soro nipa re. Weren tabi oro atoka re ni: wonyen, yii, yen, ati wonyi. Apeere:
Oro yen dun mo won ninu
Ile yii ga ju
Pasito gan-an ni mo fe ri
- EYAN ASONKA: Irufe eyan yii nii se pelu onka, o maa n toka si iye nkan ninu gbolohun. Bi apeere:
Omode meta n sere
Oko kan ni oluwa yan fun obinrin
Akara mefa ni mo je
Ile marun-un ni baba – agba ko
- EYAN ALAWE GBOLOHUN: ‘ti’ ni wunren atoka awe gbolohun asapejuwe. Ise re ni lati fi itunmo kun itumo oro – oruko ninu gbolohun. Bi apeere:
Gele ti a ran i ana wun mi
Ile ti mo ko ti kere ju
Baba ti o n soro re lo n bo yii
Ise Amutilewa
Toka orisii eyan ti o wa ninu gbolohun isale wonyii, ki o si fa ila si nidii.
- Oko wonyen ni mo fe ta
- Iyawo ti mo ni dara
- Eran dindin wu mi je
- Aso aran ni iya agba wo
- Oke meje ni a gbodo gunde ibe
- Iyana – Ipaja ti daru
- Oke nlanla wan i Efon Alaye
See also
AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)
AKORI EKO: IHUN ORISIIRISII AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN
OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI
ORISII ONA TI A N GBA SOGE NILE YORUBA
I am interested
I am interested and can I ask you some questions about the assignment giving me in school today